ALBUM

Lyrics

[Lyrics] Brymo – Okunrin Meta (Edun Okan)

Okunrin Meta (Edun Okan) Lyrics by Brymo.
Brymo – Okunrin Meta (Edun Okan) Lyrics.

We present to you the Lyrics to Brymo latest single titled ‘Okunrin Meta (Edun Okan)

For the purpose of Brymo fans and our users here we bring to you the lyrics to the song ‘Okunrin Meta (Edun Okan)‘.

In case you haven’t download the Song yet, check it out below alongside the Lyrics

Listen and Download Okunrin Meta (Edun Okan) by Brymo Below:-

Stream Music On Boomplay

also

Download The Song


Okunrin Meta (Edun Okan) Lyrics by Brymo.

Gbemi san le
Ko mi sita
Fami lewu ya
Temi lorun pa
Eniyan lasan ni mo je
Mo fuye bi paper
Iji ja lodo
O gbemi lo soko

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Olopa gba riba kasa
Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo ibi mohun lo
Edun Okan
Fun mi lokan
Okunrin meta debi ti mo n lo

Emi ni imole
Olukunkun wo gbo lo
Mo fa lewuya
Mo te lorun pa
Eniyan lasan mi o je
Mo wiwo bi ésan
Emi ni iji to ja lodo
To gboba won lo soko

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Olopa gba riba kasa
Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo ibi mohun lo
Edun Okan
Fun mi lokan
Okunrin meta debi ti mo n lo

Edun Okan
Ohun lokan
Gbemi lo sibi tokan
Oga ta Oga o ta
Okunrin meta debi ti mo n lo

Leave a Comment